Aisaya 22:14 BM

14 OLUWA àwọn ọmọ ogun ti fi tó mi létí pé:“A kò ní dárí ẹ̀ṣẹ̀ yìí jì yíntítí tí ẹ óo fi kú.”

Ka pipe ipin Aisaya 22

Wo Aisaya 22:14 ni o tọ