Aisaya 22:2 BM

2 ẹ̀yin tí ìlú yín kún fún ariwo, tí ẹ jẹ́ kìkì ìrúkèrúdò ati àríyá?Gbogbo àwọn tí ó kú ninu yín kò kú ikú idà,bẹ́ẹ̀ ni wọn kò kú lójú ogun.

Ka pipe ipin Aisaya 22

Wo Aisaya 22:2 ni o tọ