Aisaya 23:11 BM

11 OLUWA ti na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkunÓ ti mi àwọn orílẹ̀-èdè jìgìjìgì.Ó ti pàṣẹ nípa ilẹ̀ Kenaanipé kí wọ́n pa gbogbo ibi ààbò rẹ̀ run.

Ka pipe ipin Aisaya 23

Wo Aisaya 23:11 ni o tọ