Aisaya 24:13 BM

13 Bẹ́ẹ̀ ní yóo rí ní ilẹ̀ ayé,láàrin àwọn orílẹ̀-èdèbí igi olifi tí a ti gbọn gbogbo èso rẹ̀ sílẹ̀,lẹ́yìn tí a ti kórè tán ninu ọgbà àjàrà.

Ka pipe ipin Aisaya 24

Wo Aisaya 24:13 ni o tọ