Aisaya 24:6 BM

6 Nítorí náà ègún ń pa ayé run lọ.Àwọn eniyan inú rẹ̀ ń jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn,iná ń jó àwọn olùgbé inú rẹ̀,eniyan díẹ̀ ni ó sì kù.

Ka pipe ipin Aisaya 24

Wo Aisaya 24:6 ni o tọ