Aisaya 26:19 BM

19 Àwọn òkú wa yóo jí,wọn óo dìde kúrò ninu ibojì.Ẹ tají kí ẹ máa kọrin,ẹ̀yin tí ó sùn ninu erùpẹ̀.Nítorí pé ìrì ìmọ́lẹ̀ ni ìrì yín,ẹ óo sì sẹ ìrì náà sì ilẹ̀ àwọn òkú.

Ka pipe ipin Aisaya 26

Wo Aisaya 26:19 ni o tọ