Aisaya 26:21 BM

21 OLUWA óo yọ láti ibùgbé rẹ̀,láti fi ìyà jẹ àwọn tí ń gbé inú ayé, nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,ilẹ̀ yóo tú ẹ̀jẹ̀ àwọn tí wọ́n pa sórí rẹ̀ jáde,kò sì ní bo àwọn tí a pa mọ́lẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 26

Wo Aisaya 26:21 ni o tọ