Aisaya 28:14 BM

14 Nítorí náà, ẹ gbọ́ ohun tí OLUWA wí,ẹ̀yin oníyẹ̀yẹ́ eniyan,tí ẹ̀ ń ṣe àkóso àwọn eniyan wọnyi ní Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Aisaya 28

Wo Aisaya 28:14 ni o tọ