19 Gbogbo ìgbà tí ó bá ti ń ṣẹlẹ̀ni yóo máa ba yín tí yóo máa gba yín lọ.Yóo máa ṣẹlẹ̀ láàárọ̀,yóo sì máa ṣẹlẹ̀ tọ̀sán-tòru.Ẹ̀rù yóo ba eniyan,tí eniyan bá mọ ìtumọ̀ ìkìlọ̀ náà.
Ka pipe ipin Aisaya 28
Wo Aisaya 28:19 ni o tọ