Aisaya 29:1 BM

1 Ó ṣe fún Arieli, Jerusalẹmu, ìlú tí ń jẹ́ pẹpẹ Ọlọrun!Ìlú tí Dafidi pàgọ́ sí.Ẹ ṣe ọdún kan tán, ẹ tún ṣe òmíràn sí i,ẹ máa ṣe àwọn àjọ̀dún ní gbogbo àkókò wọn.

Ka pipe ipin Aisaya 29

Wo Aisaya 29:1 ni o tọ