Aisaya 30:18 BM

18 Nítorí náà OLUWA ń dúró dè yín,ó ti ṣetán láti ṣàánú yín.Yóo dìde, yóo sì ràn yín lọ́wọ́.Nítorí Ọlọrun Olódodo ni OLUWA.

Ka pipe ipin Aisaya 30

Wo Aisaya 30:18 ni o tọ