Aisaya 30:33 BM

33 Nítorí pé a ti pèsè iná ìléru sílẹ̀ láti ìgbà àtijọ́ fún ọba Asiria;iná ńlá tí ń jó pẹlu ọpọlọpọ igi.Èémí OLUWA tó dàbí ìṣàn imí-ọjọ́ ni yóo ṣá iná sí i.

Ka pipe ipin Aisaya 30

Wo Aisaya 30:33 ni o tọ