Aisaya 31:9 BM

9 Ẹ̀rù yóo ba ọba Asiria, yóo sálọ.Ìpayà yóo mú kí àwọn ọ̀gágun rẹ̀ ju àsíá sílẹ̀.OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀,OLUWA tí iná rẹ̀ wà ní Sioni,tí ojú ààrò rẹ̀ wà ní Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Aisaya 31

Wo Aisaya 31:9 ni o tọ