Aisaya 32:11 BM

11 Ẹ gbọ̀n jìnnìjìnnì, ẹ̀yin obinrin tí ara rọ̀,kí wahala ba yín, ẹ̀yin tí ẹ wà ninu ìdẹ̀ra,ẹ tú aṣọ yín, kí ẹ wà ní ìhòòhò;kí ẹ sì ró aṣọ ọ̀fọ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 32

Wo Aisaya 32:11 ni o tọ