Aisaya 32:15 BM

15 Bẹ́ẹ̀ ni nǹkan yóo rí,títí ẹ̀mí óo fi bà lé wa láti òkè ọ̀run wátítí aṣálẹ̀ yóo fi di ọgbà eléso,tí ọgbà eléso yóo sì fi di igbó.

Ka pipe ipin Aisaya 32

Wo Aisaya 32:15 ni o tọ