Aisaya 33:19 BM

19 Ẹ kò ní rí àwọn aláfojúdi náà mọ́,àwọn tí wọn ń fọ èdè tí kò ní ìtumọ̀ si yín,tí wọn ń kólòlò ní èdè tí ẹ kò gbọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 33

Wo Aisaya 33:19 ni o tọ