Aisaya 33:2 BM

2 Ṣàánú wa OLUWA,ìwọ ni a dúró tí à ń wò.Máa ràn wá lọ́wọ́ lojoojumọ,sì máa jẹ́ olùgbàlà wa nígbà ìṣòro.

Ka pipe ipin Aisaya 33

Wo Aisaya 33:2 ni o tọ