Aisaya 34:5 BM

5 Nítorí mo ti rẹkẹ idà mi lókè ọ̀run,yóo sọ̀kalẹ̀ láti ṣe ìdájọ́ àwọn ará Edomu;yóo sọ̀kalẹ̀ sórí àwọn tí mo fẹ́ parun.

Ka pipe ipin Aisaya 34

Wo Aisaya 34:5 ni o tọ