Aisaya 35:6 BM

6 arọ yóo máa fò bí ìgalà,odi yóo sì máa kọ orin ayọ̀.Nítorí odò ńlá yóo ṣàn jáde ninu aginjùàwọn odò kéékèèké yóo máa ṣàn ninu aṣálẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 35

Wo Aisaya 35:6 ni o tọ