Aisaya 35:9 BM

9 Kò ní sí kinniun níbẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni ẹranko burúkú kankan kò ní gba ibẹ̀.A kò ní rí wọn níbẹ̀,àwọn tí a ti rà pada ni yóo gba ibẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 35

Wo Aisaya 35:9 ni o tọ