Aisaya 36:3 BM

3 Eliakimu, ọmọ Hilikaya tí ó jẹ́ alákòóso ààfin jáde lọ bá wọn pẹlu Ṣebina, akọ̀wé ilé ẹjọ́, ati Joa ọmọ Asafu, akọ̀wé ààfin.

Ka pipe ipin Aisaya 36

Wo Aisaya 36:3 ni o tọ