Aisaya 38:20 BM

20 OLUWA yóo gbà mí là,a óo fi àwọn ohun èlò orin olókùn kọrin ninu ilé OLUWA,ní gbogbo ọjọ́ ayé wa.

Ka pipe ipin Aisaya 38

Wo Aisaya 38:20 ni o tọ