Aisaya 4:2 BM

2 Tí ó bá di ìgbà náà, ẹ̀ka igi OLUWA yóo di ohun ẹwà ati iyì. Èso ilẹ̀ náà yóo sì di ohun ògo ati àmúyangàn fún àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n bá kù.

Ka pipe ipin Aisaya 4

Wo Aisaya 4:2 ni o tọ