18 N óo ṣí odò lórí àwọn òkè,ati orísun láàrin àwọn àfonífojì;n óo sọ aṣálẹ̀ di adágún odò,ilẹ̀ gbígbẹ yóo sì di orísun omi.
Ka pipe ipin Aisaya 41
Wo Aisaya 41:18 ni o tọ