Aisaya 41:29 BM

29 Wò ó! Ìtànjẹ lásán ni gbogbo wọn,òfo ni iṣẹ́ ọwọ́ wọn:Ẹ̀fúùfù lásán ni àwọn ère tí wọ́n gbẹ́.”

Ka pipe ipin Aisaya 41

Wo Aisaya 41:29 ni o tọ