Aisaya 44:25 BM

25 èmi tí mo sọ àmì àwọn tí ń woṣẹ́ èké di asán,tí mo sì sọ àwọn aláfọ̀ṣẹ di òmùgọ̀.Mo yí ọgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n pomo sì sọ ọgbọ́n wọn di òmùgọ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 44

Wo Aisaya 44:25 ni o tọ