Aisaya 45:12 BM

12 Èmi ni mo dá ayé,tí mo dá eniyan sórí rẹ̀.Ọwọ́ mi ni mo fi ta ojú ọ̀run bí aṣọ,tí mo sì pàṣẹ fún oòrùn, òṣùpá ati àwọn ìràwọ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 45

Wo Aisaya 45:12 ni o tọ