Aisaya 45:16 BM

16 Gbogbo àwọn oriṣa ni a óo dójú tì,ìdààmú yóo sì bá wọn.Gbogbo àwọn tí ń gbẹ́ èreyóo bọ́ sinu ìdààmú papọ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 45

Wo Aisaya 45:16 ni o tọ