11 Mo pe idì láti ìlà oòrùn,mo sì ti pe ẹni tí yóo mú àbá mi ṣẹ láti ilẹ̀ òkèèrè wá.Mo ti sọ̀rọ̀, n óo sì mú un ṣẹ,mo ti ṣe ìpinnu, n óo sì ṣe é.
Ka pipe ipin Aisaya 46
Wo Aisaya 46:11 ni o tọ