Aisaya 5:11 BM

11 Ègbé ni fún àwọn tí wọ́n jí ní òwúrọ̀ kutukutu,láti máa wá ọtí líle kiri,tí wọ́n ń mu ún títí di ìrọ̀lẹ́,títí tí ọtí yóo fi máa pa wọ́n!

Ka pipe ipin Aisaya 5

Wo Aisaya 5:11 ni o tọ