Aisaya 5:13 BM

13 Nítorí náà àwọn eniyan mi óo lọ sí oko ẹrú nítorí àìmòye wọn,ebi ni yóo pa àwọn ọlọ́lá wọn ní àpakú,òùngbẹ óo sì gbẹ ọpọlọpọ wọn.

Ka pipe ipin Aisaya 5

Wo Aisaya 5:13 ni o tọ