Aisaya 5:23 BM

23 Àwọn tí wọn ń dá ẹni tí ó jẹ̀bi sílẹ̀nígbà tí wọ́n bá ti gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ tán;tí wọn kì í jẹ́ kí aláìṣẹ̀ rí ẹ̀tọ́ gbà.

Ka pipe ipin Aisaya 5

Wo Aisaya 5:23 ni o tọ