Aisaya 52:10 BM

10 OLUWA yóo lo agbára mímọ́ rẹ̀, lójú àwọn orílẹ̀-èdè,gbogbo eniyan, títí dé òpin ayé, yóo sì rí ìgbàlà Ọlọrun wa.

Ka pipe ipin Aisaya 52

Wo Aisaya 52:10 ni o tọ