Aisaya 52:5 BM

5 Ṣugbọn nisinsinyii, kí ni mo rí yìí? Wọ́n mú àwọn eniyan mi lọ lọ́fẹ̀ẹ́, àwọn alákòóso wọn ń pẹ̀gàn, orúkọ mi wá di nǹkan yẹ̀yẹ́?

Ka pipe ipin Aisaya 52

Wo Aisaya 52:5 ni o tọ