Aisaya 55:13 BM

13 igi Sipirẹsi ni yóo máa hù dípò igi ẹlẹ́gùn-ún,igi Mitili ni yóo sì máa hù dípò ẹ̀gún ọ̀gàn,yóo jẹ́ àmì ìrántí fún OLUWA,ati àpẹẹrẹ ayérayé tí a kò ní parẹ́.”

Ka pipe ipin Aisaya 55

Wo Aisaya 55:13 ni o tọ