3 Kí àjèjì tí ó faramọ́ OLUWA má sọ pé,“Dájúdájú OLUWA yóo yà mí kúrò láàrin àwọn eniyan rẹ̀.”Kí ìwẹ̀fà má sì sọ pé,“Wò ó! Mo dàbí igi gbígbẹ.”
Ka pipe ipin Aisaya 56
Wo Aisaya 56:3 ni o tọ