Aisaya 57:1 BM

1 Olódodo ń ṣègbé,kò sí ẹni tí ó fi ọkàn sí i.A mú àwọn olótìítọ́ kúrò, kò sì sí ẹni tí ó yé,pé à ń yọ olódodo kúrò ninu ìdààmú ni.

Ka pipe ipin Aisaya 57

Wo Aisaya 57:1 ni o tọ