Aisaya 57:20 BM

20 Ṣugbọn àwọn eniyan burúkú dàbí ríru omi òkun,nítorí òkun kò lè sinmi,omi rẹ̀ a sì máa rú pàǹtí ati ẹrẹ̀ sókè.

Ka pipe ipin Aisaya 57

Wo Aisaya 57:20 ni o tọ