12 Ẹ óo tún odi yín tí ó ti wó lulẹ̀ mọ,ẹ óo sì gbé àwọn ìpilẹ̀ṣẹ̀ àtijọ́ dìde.Àwọn eniyan yóo máa pè yín ní alátùn-únṣe ibi tí odi ti wó,alátùn-únṣe òpópónà àdúgbò fún gbígbé.
Ka pipe ipin Aisaya 58
Wo Aisaya 58:12 ni o tọ