Aisaya 58:14 BM

14 nígbà náà ni inú yín yóo máa dùn láti sin èmi OLUWA,n óo gbe yín gun orí òkè ilẹ̀ ayé,n óo sì mu yín jogún Jakọbu, baba ńlá yín.Èmi OLUWA ni ó sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Aisaya 58

Wo Aisaya 58:14 ni o tọ