Aisaya 59:12 BM

12 “Nítorí àìdára wa pọ̀ níwájú rẹ,ẹ̀ṣẹ̀ wa sì ń jẹ́rìí lòdì sí wa;nítorí àwọn àìdára wa wà pẹlu wa,a sì mọ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa:

Ka pipe ipin Aisaya 59

Wo Aisaya 59:12 ni o tọ