20 OLUWA ní, “N óo wá sí Sioni bí Olùràpadà,n óo wá sọ́dọ̀ àwọn ọmọ Jakọbu,tí wọ́n yipada kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀.
Ka pipe ipin Aisaya 59
Wo Aisaya 59:20 ni o tọ