Aisaya 6:13 BM

13 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìdámẹ́wàá àwọn eniyan náà ni ó kù ní ilẹ̀ náà, sibẹsibẹ iná yóo tún jó o bí igi terebinti tabi igi Oaku, tí kùkùté rẹ̀ wà lórí ilẹ̀ lẹ́yìn tí wọ́n gé e lulẹ̀.”Èso mímọ́ ni kùkùté rẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 6

Wo Aisaya 6:13 ni o tọ