Aisaya 61:4 BM

4 Wọn óo tún àlàpà ahoro àtijọ́ kọ́,wọn óo tún gbogbo ilé tí ó ti wó lulẹ̀ kọ́,wọn óo sì tún ìlú tí a ti parun láti ọdún gbọọrọ kọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 61

Wo Aisaya 61:4 ni o tọ