Aisaya 63:10 BM

10 Ṣugbọn wọ́n hùwà ọlọ̀tẹ̀:wọ́n sì mú Ẹ̀mí Mímọ́ rẹ̀ bínú.Nítorí náà ó di ọ̀tá wọn,ó sì dojú ìjà kọ wọ́n.

Ka pipe ipin Aisaya 63

Wo Aisaya 63:10 ni o tọ