Aisaya 64:11 BM

11 Wọ́n ti dáná sun ilé mímọ́ wa tí ó lẹ́wà,níbi tí àwọn baba wa ti yìn ọ́,gbogbo ibi dáradára tí a ní, ló ti di ahoro.

Ka pipe ipin Aisaya 64

Wo Aisaya 64:11 ni o tọ