7 Kò sí ẹnìkan tí ń gbadura ní orúkọ rẹ,kò sí ẹni tí ń ta ṣàṣà láti dìmọ́ ọ;nítorí pé o ti fojú pamọ́ fún wa,o sì ti pa wá tì nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa.
Ka pipe ipin Aisaya 64
Wo Aisaya 64:7 ni o tọ