Aisaya 64:9 BM

9 OLUWA má bínú pupọ jù,má máa ranti ẹ̀ṣẹ̀ wa títí lae.Jọ̀wọ́, ro ọ̀rọ̀ wa wò,nítorí pé eniyan rẹ ni gbogbo wa.

Ka pipe ipin Aisaya 64

Wo Aisaya 64:9 ni o tọ