Aisaya 65:3 BM

3 tí wọn ń ṣe ohun tí yóo mú mi bínú,níṣojú mi, nígbà gbogbo.Wọ́n ń rúbọ ninu oríṣìíríṣìí ọgbà,wọ́n ń sun turari lórí bíríkì.

Ka pipe ipin Aisaya 65

Wo Aisaya 65:3 ni o tọ