Aisaya 66:2 BM

2 Ọwọ́ mi ni mo fi ṣe gbogbo nǹkan wọnyi,tèmi sì ni gbogbo wọn.Ẹni tí n óo kà kún,ni onírẹ̀lẹ̀ ati oníròbìnújẹ́ eniyan, tí ó ń wárìrì nítorí ọ̀rọ̀ mi.

Ka pipe ipin Aisaya 66

Wo Aisaya 66:2 ni o tọ